Pages: [1]
  Print  
Author Topic: Omo Kaaro OOjire.  (Read 2668 times)
0 Members and 1 Guest are viewing this topic.
globalaid
Sophomore
**
Offline Offline

Posts: 17


« on: October 01, 2007, 02:27:14 PM »

Kilo de, se ko si Yoruba nibi ni?
Logged
kago
Freshman
*
Offline Offline

Posts: 2


« Reply #1 on: February 28, 2010, 08:53:49 PM »

E nle nbeun o.

Kii se wipe ko si Yoruba ni ile yi, ede abinibi wa ko wu awon omo wa so mo nii! O se ni laanu pupo. Kii se ni ile yi nikan, ni ile Nigeria gaan awon ewe o fe so ede Youba mo. Geesi ni gbogo won fee maa so. Opo won o si gbo Geesi naa daradara.
Logged
Pages: [1]
  Print  
 
Jump to:  

Powered by MySQL Powered by PHP Powered by SMF 1.1.11 | SMF © 2006-2009, Simple Machines LLC Valid XHTML 1.0! Valid CSS!